Sísẹ́ agbeyewo litireso apileko

Akekoo yoo le:
Se ìdámọ̀ awon àbùdá ti yoo maa kiyesii ninu litireso apileko ti o fe se agbeyewo re.
Ko oye re nipa awon àbùdá yii láti jiroro nipa / se agbeyewo litireso apileko.

Leta kiko

Akekoo yoo le:
So orisii leta méjì to wa: gbefe àti aigbagbefe.
So ìyàtọ̀ àárín won
Ko orisi leta mejeeji

Akotó

So ohùn ti akotó je.
So ìyàtọ̀ laarin akotó odè oni ati ti atijo.
Se amulo akoto ode oni ninu kiko oro sile

Akaye

Kàwé sinu.
Fa koko oro inu àyoka yo nipa d ìdáhùn ibeere ni oro enu ati kiko.

Themes

The Themes in the Drama: She Stoops to Conquer by Oliver Goldsmith