Akaye

Akekoo yoo le:
kàwé sinu
Fa koko inu akaye yo nipa dìdáhùn ibeere lori re.
So itumo awon akánlo ede inu àyoka.

Iranra-eni lowo

Akekoo yoo le salaye:
Kin ni àsà iranra-eni lowo?
Nipa ise ajumose ati oro aje.

Ayéye ibile yorùba isomoloruko

Akekoo yoo le:
Salaye eto isomoloruko ni sise-n-tele.
So orisiirisi oruko ti yorùba n so omo won ati idi ti won fi n so omo won bee.

Ogun ati alaafia

Akekoo yoo le:
So die nipa ogun yorùba laye àtijo :
• Oruko awon ògun ti won ja
• Awon jagunjagun
• Ohun elo ìjagun.
Anfaani ogun jija
Ona lati dekun ogun abi lati wa alaafia.

Esin ibile

Akekoo yoo le salaye:
Ipa esin lawujò.
Ipo Olodumare ati awon orisa ninu esin yorùba.
Ipa pataki ti esin ko ninu ojuse awon yorùba si ara won.

Ewi Alohùn Arangbo:

Akekoo yoo le:
Daruko ewi alohùn arangbo die
Se alaye ọ̀gangan ipo ati ihun won

Orin

Akekoo yoo le:
Ko orin ibile yorùba díẹ̀.
Se àlàyé ọ̀gangan ipo re
So koko oro ti orin kookan da le.
Jiroro nipa ewa ede inu awon orin naa.

Asayan iwe àyoka-itan Aroso oloro geere

Akekoo yoo le:
Ka iwe ti a ba yan ni akadanmoran ati akaye;
ki;
Tun itan ti won ka so ni soki;
Se àyẹ̀wò awon koko-oro to súyo.
Daruko awon eda itan, ki o si salaye nipa Ifiwaweda won.
Se alaye nipa ilo ede.

Asayan iwe àyokà (Ewi)

Akekoo yoo le:
Ka awon ewi naa ni akadanmoran ati akaye.
So ohun ti won gbádùn ninu ewi kookan ti won ka ati idi ti won fi gbádùn re.
Toka si ewa ede to sùyo ninu awon ewi naa

Asayan iwe àyokà

Akekoo yoo le:
Ka iwe ti a ba yan ni akaye, ki o si dan moran;
So orisiirisi eko ti ere inu iwe naa ni (koko oro);
So itan ere naa ni soki (àhunpò itan ihun);
Daruko awon eda itan inu iwe ere naa ki o si salaye Ifiwaweda won.
So awon ilu, adugbo ati ibi ti isele inu ere naa ti sele
Kopa ninu isere

Orisiirisii gbolohun (ihun)

Akekoo yoo le
Se ìdámọ̀ gbolohun alábọ́dé, alakanpo ati oníbọ̀.
Se àpẹẹrẹ orisii awon gbolohun meteeta naa.

Ihun oro

Akekoo yoo le se ìdámọ̀ orisiirisi bátànì ihun oro yorùba.

Isori oro

Akekoo yoo le:
Daruko awon isoro oro yorùba;
Toka si isori kookan ninu gbolohun.
So ise ti okookan n se ninu gbolohun

Ìtẹ̀síwájú Iro Ede Ami Ohun

Akekoo yoo le:
Se ìdámọ̀ ami fun ikookan ohun Yorubá meteeta.
Pe awon ohun naa lori oro oni eyo silebu ati ọlópọ̀ silebu.
Fi ami ohun si ori oro bi o ti ye.

Igbeyawo

Akekoo yoo le:
So orisiirisii ilana ti a n tele ninu asà igbeyawo ni ile yorùba:
Fi igbeyawo ibile yorùba we ti ode oni;
Salaye ewu to ro mo ailekora-eni-ni ijanu nipa ibalopo saaju igbeyawo