Awon eya yorùba

Akekoo yoo le:
So nipa awon eya yorùba;
Toka si awon agbegbe ti won wa ninu maapu.
Isedale àti itankale omo yorùba

So itan isedale omo yorùba;
Se àlàyé bi won se tan kale de ibi ti won wa loní.
Isori-isori litireso alohùn

Akekoo yoo le:
So ohun ti litireso alohùn je.
Se alaye nipa awon isori-isori ti litireso alohùn pin si.
Awon isori litireso apileko

Akekoo yoo le:
So ohun ti litireso apileko je.
Salaye nipa isori-isori litireso apileko.
Sísẹ́ agbeyewo litireso alohùn

So àbùdá pataki ti o mu ki agbeyewo litireso alohùn yato si ti apileko (ọ̀gangan-ipo).
Darukọ awon abuda ọ̀gangan-ipo.
Sísẹ́ agbeyewo litireso apileko

Akekoo yoo le:
Se ìdámọ̀ awon àbùdá ti yoo maa kiyesii ninu litireso apileko ti o fe se agbeyewo re.
Ko oye re nipa awon àbùdá yii láti jiroro nipa / se agbeyewo litireso apileko.
Iseda Orò –Orúkọ

Akekoo yoó le so orisiirisii ona ti a n gba ṣẹ̀dà oro oruko
Leta kiko

Akekoo yoo le:
So orisii leta méjì to wa: gbefe àti aigbagbefe.
So ìyàtọ̀ àárín won
Ko orisi leta mejeeji
Àrokò (Oniroyin )

Ko aroko oniroyin nipa titele ìlànà ti oluko fi lelé
Akotó

So ohùn ti akotó je.
So ìyàtọ̀ laarin akotó odè oni ati ti atijo.
Se amulo akoto ode oni ninu kiko oro sile
Akaye

Kàwé sinu.
Fa koko oro inu àyoka yo nipa d ìdáhùn ibeere ni oro enu ati kiko.
Onka ookanleleede-gbeta de egberun (501-1000)

Ka onka lati ookanleleedegbeta de egberun (501 – 1000)
Da figo awon onka naa mo (501 – 1000)
Iro ede (Konsonanti ati Faweli)

Akekoo yoo le:
Se idámo,
Ka,
Ko awon leta iro ede Yoruba
Collage Production

At the end of this lesson, the students should be able to understand Collage Production
Modelling With Paper Mache

At the end of this lesson, the students should be able to understand how to Model With Paper Mache
Drug Traffiking

At the end of this lesson, the students should be able to understand Drug Traffiking
Social Conflicts (II)

At the end of the lesson, the student should be able to understand more on Social Conflicts
Preventing Drug Trafficking.

state the meaning of drug trafficking;
identify reasons for trafficking in drugs;
describe the dangers of drug trafficking;
identify ways for preventing drug trafficking
Controlling Cultism in our Society.

define cultism;
identify causes of cultism;
describe the consequences of cultism;
Proffer solutions to the problems of cultism in Nigeria.
Managing and Resolving Conflicts

suggest non-violent methods of resolving Conflicts.
explain that resolution of conflicts enhances national peaceful coexistence.