Ijenlearofo Ewi Yoruba Meedogbon

Daruko ewi mewaa ti a menu ba
So koko oro ewi kookan
So iru ewi wo lo kilo iwa
Daruko ewi to ni ka sora fun iru ore ti a ma ba rin
Daruko ewi to soro nipa ife
So koko oro ewi ka wi fun ni ka fe
Ise oro arọ́pò oruko ati oruko ninu gbolohun.

Akekoo yoo le so ise ti oro oruko ati arọ́pò oruko n se ninu gbolohun.
Akoko siwaju si i

Akekoo yoo le so awon ìpinnu ijoba apapo ti odun 1974 lori akoto ede yorùba
Onka lati egbaa (2000) De egbaawaa (20,000)

Akekoo yoo le:
Ka onka lati egbaa (2000)
De egbaawaa (20,000)
Da figo awon onka naa mo.
Akaye

Akekoo yoo le:
kàwé sinu
Fa koko inu akaye yo nipa dìdáhùn ibeere lori re.
So itumo awon akánlo ede inu àyoka.
Asayan Ere Onise

Asayan Ere Onise
Iranra-eni lowo

Akekoo yoo le salaye:
Kin ni àsà iranra-eni lowo?
Nipa ise ajumose ati oro aje.
Ayéye ibile yorùba isomoloruko

Akekoo yoo le:
Salaye eto isomoloruko ni sise-n-tele.
So orisiirisi oruko ti yorùba n so omo won ati idi ti won fi n so omo won bee.
Ogun ati alaafia

Akekoo yoo le:
So die nipa ogun yorùba laye àtijo :
• Oruko awon ògun ti won ja
• Awon jagunjagun
• Ohun elo ìjagun.
Anfaani ogun jija
Ona lati dekun ogun abi lati wa alaafia.
Esin ibile

Akekoo yoo le salaye:
Ipa esin lawujò.
Ipo Olodumare ati awon orisa ninu esin yorùba.
Ipa pataki ti esin ko ninu ojuse awon yorùba si ara won.
Isori Lisorilitireso Alohun

Isori Lisorilitireso Alohun
Ewi Alohùn Arangbo:

Akekoo yoo le:
Daruko ewi alohùn arangbo die
Se alaye ọ̀gangan ipo ati ihun won
Ìsáré/Ajemesin ati Ajemayeye/ Alaijemesin

Akekoo yoo le:
Daruko ìsáré ajemesin ati ayéye tabi alaijemesin die
Se alaye ọ̀gangan ipo okòòkan.
Orin

Akekoo yoo le:
Ko orin ibile yorùba díẹ̀.
Se àlàyé ọ̀gangan ipo re
So koko oro ti orin kookan da le.
Jiroro nipa ewa ede inu awon orin naa.
Asayan iwe àyoka-itan Aroso oloro geere

Akekoo yoo le:
Ka iwe ti a ba yan ni akadanmoran ati akaye;
ki;
Tun itan ti won ka so ni soki;
Se àyẹ̀wò awon koko-oro to súyo.
Daruko awon eda itan, ki o si salaye nipa Ifiwaweda won.
Se alaye nipa ilo ede.
Asayan iwe àyokà (Ewi)

Akekoo yoo le:
Ka awon ewi naa ni akadanmoran ati akaye.
So ohun ti won gbádùn ninu ewi kookan ti won ka ati idi ti won fi gbádùn re.
Toka si ewa ede to sùyo ninu awon ewi naa
Asayan iwe àyokà

Akekoo yoo le:
Ka iwe ti a ba yan ni akaye, ki o si dan moran;
So orisiirisi eko ti ere inu iwe naa ni (koko oro);
So itan ere naa ni soki (àhunpò itan ihun);
Daruko awon eda itan inu iwe ere naa ki o si salaye Ifiwaweda won.
So awon ilu, adugbo ati ibi ti isele inu ere naa ti sele
Kopa ninu isere
Orisiirisii gbolohun (ihun)

Akekoo yoo le
Se ìdámọ̀ gbolohun alábọ́dé, alakanpo ati oníbọ̀.
Se àpẹẹrẹ orisii awon gbolohun meteeta naa.
Ihun oro

Akekoo yoo le se ìdámọ̀ orisiirisi bátànì ihun oro yorùba.
Isori oro

Akekoo yoo le:
Daruko awon isoro oro yorùba;
Toka si isori kookan ninu gbolohun.
So ise ti okookan n se ninu gbolohun