Ìró Èdè

Ìró Èdè
Ìtọ́jú Ara Àti Ìtọ́jú Ọmọ

Ìtọ́jú Ara Àti Ìtọ́jú Ọmọ
Òwe Àti Àkànlò Ède

Òwe Àti Àkànlò Ède
Àkàyé

Àkàyé
Owo sise Ni Ile Yoruba

Akekoo yoo le:
So ohun ti owo sise je.
Salaye ipa ti owo sise ko ninu oro aje yorùba.
Salaye nipa orisiirisii owo ni ile yorùba
So bi a se le din arósese ku lode oni tabi ki a dekun re nipase owo sise.
Aroko Aye Atijo

At the end of the lesson, the student should be able to understand Aroko Aye Atijo
Aroko

Akekoo yoo le:
So ohun ti aroko je.
Daruko die ninu awon ami aroko.
Itoju aláboyún

Akekoo yoo le:
Salaye lori asà oyun nini ati itoju oyun;
So awon ohun to le dena oyun nini;
So ohun to le fa bibi abiku.
Esin ibile yorùba siwaju si i (ohun mimo)

Akekoo yoo le:
Se alaye nipa igbagbo awon yorùba lori ohun mimo bi o se súyo ninu esin ibile.
Fi awon ohun to mo ninu esin ibile se iwa hu
Didekun iwa ika si omolakeji

Akekoo yoo le:
So die lara iwa ika si omolakeji ti o wopo latijo ati lode oni.
So die lara-ona ti a le fi dekun iwa bee lawujo.
Agbeyewo Akoto siwa’ju’si

At the end of this lesson, student should be able to:.
Asayan iwe itan aroso oloro geere

Akekoo yoo le:
Tun itan so ni soki
So ibudo itan.
So koko ti itan naa dale
Salaye ona-ede ati isowolo ede.
Salaye nipa eda itan ati ifiwaweda won.
Asayan iwe ewi

Akekoo yoo le:
Ka awon ewi naa dan moran
Se ìdámọ̀ ona ede ati isowolo ede inu ewi naa;
Fa awon koko oro ibe yo.
Asayan iwe ere onítan

Akekoo yoo le:
Fa eko ti ere naa ko ni yo
Salaye ifiwaweda ibe.
Salaye ilo ede
Se afiwe isele inu ere ati isele oju aye
Kopa ninu isere
Ijenlearofo Ewi Yoruba Meedogbon (II)

Daruko ewi mewaa ti a menu ba
So koko oro ewi kookan
So iru ewi wo lo kilo iwa
Daruko ewi to ni ka sora fun iru ore ti a ma ba rin
Daruko ewi to soro nipa ife
So koko oro ewi ka wi fun ni ka fe
Ijenlearofo Ewi Yoruba Meedogbon

Daruko ewi mewaa ti a menu ba
So koko oro ewi kookan
So iru ewi wo lo kilo iwa
Daruko ewi to ni ka sora fun iru ore ti a ma ba rin
Daruko ewi to soro nipa ife
So koko oro ewi ka wi fun ni ka fe
Ise oro arọ́pò oruko ati oruko ninu gbolohun.

Akekoo yoo le so ise ti oro oruko ati arọ́pò oruko n se ninu gbolohun.
Akoko siwaju si i

Akekoo yoo le so awon ìpinnu ijoba apapo ti odun 1974 lori akoto ede yorùba
Onka lati egbaa (2000) De egbaawaa (20,000)

Akekoo yoo le:
Ka onka lati egbaa (2000)
De egbaawaa (20,000)
Da figo awon onka naa mo.
Akaye

Akekoo yoo le:
kàwé sinu
Fa koko inu akaye yo nipa dìdáhùn ibeere lori re.
So itumo awon akánlo ede inu àyoka.